GLyr

Asa – Eyé Àdabá

Singers: Asa
Albums: Asa – Asa - Aṣa
song cover

Lyrics Asa – Eyé Àdabá

Text:

Oju mo ti mo
Oju mo ti mo mi
Ni le yi o o
Oju mo ti mo — mo ri re o

Eye adaba
Eye adaba
Eye adaba ti n fo lo ke lo ke
Wa ba le mi o o
Oju mo ti mo mo ri re o

Album

Asa – Asa - Aṣa